Versos de Ìwòrì Òfún en Iwori-Ofun
Ir a la navegación
Ir a la búsqueda
Versos de Ìwòrì Òfún en Iwori-Ofun
Enini bélébélé níí werí emó
Tòtò bàlàbàlà níí wèdí àdán
Agemo òògùn níí werí Olójà mérìndínlógún nínú ajere ide
A díá fún Ìwòrì
Níjó ti n lo rèé werí Òfún
“Orí Òfún le dáa báyìí”?
Wón ní kí Òfún ó to Ìwòrì lo
Ìwòrí bá werí Òfún
Òfún bá n lájé
Òfún n láya
Òfún n níre gbogbo
Òpò Eku lebo
Òpò Àdán lebo
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Enini bélébélé níí werí emó
Tòtò bàlàbàlà níí wèdí àdán
Agemo òògùn níí werí Olójà mérìndínlógún nínú ajere ide
A díá fún Ìwòrì
Níjó ti n lo rèé werí Òfún
Ìwòrì wòfún ní ó weríi mi nmi
Weríi mi nmi ò
Awedewèlèkè
Weríi mi sájé
Awedewèlèkè
Weríi mi sáya
Awedewèlèkè
Weríi mi sómo
Awedewèlèkè
Eni Ìwòrìwòfún bá wè ló mó roro
Awedewèlèkè.
Véase Iwori-Ofun.