Versos de Òsòló awo Awòn en Obara-Meyi

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Versos de Òsòló awo Awòn en Obara-Meyi

Òsòló Awo Awòn
Ló díá fún Awòn
Níjó tí n lo rèé werí Olà lódò
Ará ro Òun báyìí?
Wón lára ó rò ó
Wón ní sùgbón kó rúbo fún Òsun
Ó bá rúbo
Ará bá dè é
Ní bá n bímo
Ló bá kó omo è lo fún Òsun
Wón níkú ò gbodò pa omo Awòn
Ayé ye é
Òsun n tójú è
Ní n gè é
N ní wá n jó n ní n yò
Ní n yin Àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òsòló Awo Awòn
Ló díá fún Awòn
Níjó tí n lo rèé werí Olà lódò
Òsòló mòmò dé ò
Awo Awòn
E ò mò pÓrí rere lÀwòn n wè?

Véase Obara-Meyi.