Versos Eruku tóróró en Ofun-Meyi

De IFA Wiki
Revisión del 10:18 29 nov 2026 de Maintenance script (discusión | contribuciones) (Ampliación del odu y sus referencias internas; revisión de textos y enlaces.)
(dif) ← Revisión anterior | Revisión actual (dif) | Revisión siguiente → (dif)
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Versos Eruku tóróró en Ofun-Meyi

Eruku tóróró
Eruku tàràrà
A díá fún Èjì òràngún
Èjì òràngún tí n sawo re Ilé ìlasàn
Ebo n wón ní ó se
Ó sì gbébo nbè
Ó rúbo
Ìgbà Èjì òràngún sawo dé Ilé ìlasàn la rájé
Eruku tóróró
Eruku tarara
Ìgbà Èjì òràngún sawo dé Ilé ìlasàn la láya
Eruku tóróró
Eruku tàràrà
Ìgbà Èjì òràngún sawo dé Ilé ìlasàn la dolómo
Eruku tóróró
Eruku tàràrà
Ìgbà Ejì òràngún sawo dé Ilé ìlasàn la doníre gbogbo
Eruku tóróró
Eruku tàràrà.

Véase Ofun-Meyi.