Verso de Òpìnmí en Iroso-Irete
Verso de Òpìnmí en Iroso-Irete
Igi àjùbà ni ń mì jóńgò jóńgò
A dífá fún Òpìnmí
Ti ń bo Ikin è tí ń bo Òsun nítorí omo
Wón ní kó rúbo
Wón nire gbogbo fún un
Wón ní gbogbo ire ní ó sùn ún bò
Ajé ni
Omo
Aya
Sùgbón kó da Ifá àti Òsun pò sójú kan
Kó sì bo wón papò
Ó bá rúbo
Ayé bá ye é
N ní wá ń jó ní ń yò
Ní ń yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo ń yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Igi àjùbà ni ń mì jóńgò jóńgò
A dífá fún Òpìnmí
Ti ń bo Ikin è tí ń bo Òsun nítorí omo
Ìgbà Òpìnmí ń bo Ikin è tí ń bÒsun la rájé
Ìgbà Òpìnmí ń bo Ikin è tí ń bÒsun la ráya
Ìgbà Òpìnmí ń bo Ikin è tí ń bÒsun la bímo
Ìgbà Òpìnmí ń bo Ikin è tí ń bÒsun la kólé
Mo mòmò yin igi àjùbà tí ń mi jóńgò jóńgò
Òpìnmí tí ń bo Ikin è
Ń tí ń bÒsun.
Ifá predice para esta persona la buena fortuna de hijos. Una Gallina, un Pez y Aceite de palma es el sacrificio. La persona simultáneamente hará sacrificio a Ifá y a Òsun en una misma sopera o Jícara para que sus cosas puedan resolverse.
Igi àjùbà ni ń mì jóńgò jóńgò
Hizo adivinación para Òpìnmí
Cuando sacrificaría a su Ikin y a Òsun para tener hijos
El fue aconsejado hacer sacrificio
Para que todas las buenas fortunas sean abundantes
Ya sea riqueza
Esposas
Hijos
Pero el deberá juntar a Ifá y a Òsun en una sopera o Jícara
Y ofrecer sacrificio a ellos simultáneamente
Él hizo el sacrificio
La vida de él fue placentera
El comenzó a alabar a su Babaláwo
Su Babaláwo alabó a Ifá
El dijo que fue exactamente como su Babaláwo había dicho
Igi àjùbà ni ń mì jóńgò jóńgò
Hizo adivinación para Òpìnmí
Cuando sacrificaría a su Ikin y a Òsun para tener hijos
Fue cuando Òpìnmí sacrificó a su Ikin y a Òsun que tuvimos riqueza
Fue cuando Òpìnmí sacrificó a su Ikin y a Òsun que tuvimos esposas
Fue cuando Òpìnmí sacrificó a su Ikin y a Òsun que tuvimos casa
Yo te alabo Igi àjùbà ni ń mì jóńgò jóńgò
Òpìnmí ha estado rindiendo culto a su Ikin
El había estado rindiendo culto a Òsun.
Véase Iroso-Irete.