Verso de Onílée káà y Onílé Kótó en Oshe-Ojuani

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Verso de Onílée káà y Onílé Kótó en Oshe-Ojuani

Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
A díá fún Onílée káà
A bù fún Onílé Kótó
Wón ní wón ó rúbo
Ó dáa fún àwon báyìí?
Ayé ye àwon báyìí?
Wón ní yóó dáa fún won
Sùgbón kí wón ó rúbo
À á séé mo Onílée káà
N làá pe Sàngó
Sàngó rúbo
Ló bá gba Káà
Ni Sàngó jókòó n Káà
Ní n fèyìn tì
Ayé ye é
N ní wá n jó ní wá n yò
Ní n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
A díá fún Onílée káà
A bù fún Onílé Kótó
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
Èyin ò mò pÓnílée Káà ni Sàngó?
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon.

Ifá desea la buena fortuna de construir una casa a esta persona. Dice Ifá que le tendrá paz mental.

Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
Fue quien hizo adivinación para Onílée káà
Y también para Onílé Kótó
Ellos fueron aconsejados ofrecer sacrificio
‘¿Nuestras vidas serán buenas del todo?’
‘¿Será placentera para nosotros?’
Ellos le aseguraron que todo estaría bien para ellos
Pero que deben ofrecer el sacrificio
¿Como sabemos quién es Onílé Káà?
Es un alías de Sàngó
Sàngó realizó el sacrificio
El se hizo cargo de la sala de estar
Y se sintió confortante
Y también estaba descansando allí
La vida lo complació
Él luego comenzó a bailar y estaba muy feliz
Él estaba alabando a sus Babaláwos
Y sus Babaláwos alababan a Ifá
Él dijo que fue exactamente como sus Babaláwos habían dicho
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
Fue quien hizo adivinación para Onílée káà
Y también para Onílé Kótó
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon
Usted no sabía que Sàngó es Onílé Káà
Òsé wonrín wonrìn wonnwonntíwon.

Véase Oshe-Ojuani.