Versos de Ìwòrì Òsá en Iwori-Osa

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Versos de Ìwòrì Òsá en Iwori-Osa

Gbàbilà Gbàbilà
A díá fún Ìwòrì
Èyí ti n relé Òsá rèé kájé wálé
Wón ní kó rúbo
Wón ní kó mó báàyàn jà
Kó sì mó bénìkan bínú
Nígbà ti ajé ó bérè
Ilé Òsá ló ti bèrè
Ìwòrí rájé kó wálé
Inú è é dùn
N ní wán n jó ní wá n yò
Ní n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Gbàbilà Gbàbilà
A díá fún Ìwòrì
Èyí ti n relé Òsá rèé kájé wálé
Gbàbilà omo olówó eyo
Ìwòrì ló loolé Òsá lòó kájé wálé
Gbàbilà omo olówó eyo.

Véase Iwori-Osa.