Versos de Òbàrà bo bòó y Ekòló en Obara-Ogbe

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Versos de Òbàrà bo bòó y Ekòló en Obara-Ogbe

Òbàrà bo bòó
A díá fún Ekòló
Níjó tí n fomi ojú sògbérè omo
Wón ní ko rúbo
Wón níre omo fún un
Wón ní omo tí ó bìí ó pò
Ekòló bá lo ìsàlè odò
Ní pèrèpèrè àbàtà
Ó bá lòó lóko
Ekòló bá bèrè síí bímo níbè
Ayé ye Ekòló
N ní wá n jó n ní n yò
Ní n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òbàrà bo bòó
A díá fún Ekòló
Níjó tí n fomi ojú sògbérè omo
Wón ní ko rúbo
Ó wáá gbébo nbè
Ó wáá rúbo
Ló wáá bèrè síí yin Òbàrà bo bòó, nísàlè àbàtà
A lóun yin Òbàrà bo bòó
Bòó bobòó, bòó.

Véase Obara-Ogbe.