Aláaka káwó ikú
Ir a la navegación
Ir a la búsqueda
Aláaka káwó ikú
En Ika-Ika
En Verso de Káwó fún mi en Ika-Ika:
Káwó fún mi
Kí n kásè fún o
A díá fún Oníkàámògún
Omo Aláaka káwó ikú
Wón ní ó sá káálè Ebo ní ó se
Wón ní ó fi Aaka kún Ebo è rú
Kò kú
Kò rùn
Kà sàì kábi kúò
Akika
Akika kà sàì kábi kúò
Akika.
Véase Ika-Ika.