Dèndèré
En Verso de Dèndèré en Ika-Ofun:
Orí Ìká fún Orí Ìká ò fún Orí eni níí fún ni níre A díá fún Dèndèré Èyí tíí se iye Osù lórun Òun le níre báyìí? Ire jókòó ti òun báyìí? Wón lébo ni kó rú
Véase Ika-Ofun.