Dèndèré

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Dèndèré

En Ika-Ofun

En Verso de Dèndèré en Ika-Ofun:

Orí Ìká fún
Orí Ìká ò fún
Orí eni níí fún ni níre
A díá fún Dèndèré
Èyí tíí se iye Osù lórun
Òun le níre báyìí?
Ire jókòó ti òun báyìí?
Wón lébo ni kó rú

Véase Ika-Ofun.