Verso de Ika-Ojuani
Verso de Ika-Ojuani
Akòko ni gbàdàgi
A díá fún Aláaka
Ti n kómo lo rèé bÓkè
Wón ní kí Aláaká ó rúbo
Akòko ni gbàdàgí níwo Aláaka
Ire Omo n be fún o
Sùgbón lésè Òkè ni o kómoò re lo
Aláaka bá rúbo
Ó korí sí esè Òkè
Ló bá bèrè síí bímo
Ní bá n yin àwon Akòko ni gbàdàgì
Àwon Akòko ni gbàdàgì n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babálawo tòún wí
Akòko ni gbàdàgi
A díá fún Aláaka
Ti n kómo lo rèé bÓkè
Akòko ni gbàdàgì
Ìwo lawo Aláaka
Aláaká deni àbímo yè nbè
Akòko ni gbàdàgì
Ìwo lawo Aláaka.
Ifá le desea la fortuna de hijos a esta persona. Los hijos vivirán. Él no morirá prematuramente ni habrá de enfermarse.
Akòko ni gbàdàgi
Hizo adivinación para Aláaka
Quien llevaría a sus hijos para que se reunieran con Òkè
Le aconsejaron que realizara sacrificio
Akòko ni gbàdàgi la llamó ‘Usted Aláaka’
‘Hay fortunas de hijos para usted’
‘Pero usted debe llevar a sus bebés al lado de una colina’
Aláaka observó el sacrificio
Y fue a la orilla de la base de una colina
Y allí ella comenzó a tener más bebés
Ella comenzó alabar a su sacerdote
Akòko ni gbàdàgi estaba alabando a Ifá
Ella dijo que fue exactamente lo que su Babaláwo había dicho
Akòko ni gbàdàgi
Hizo adivinación para Aláaka
Quien llevaría a sus hijos para que se reunieran con Òkè Akòko ni gbàdàgi
Usted es el Babaláwo de Aláaka
Aláaka alimentó con éxito allí a sus hijos.
Véase Ika-Ojuani.