Versos de Ìwòrì Òkànràn en Iwori-Okana

De IFA Wiki
Ir a la navegación Ir a la búsqueda

Versos de Ìwòrì Òkànràn en Iwori-Okana

Ìwòrì ò rinkàn
Awo Olórèé Àgbon
A díá fún Ináagún
Níjó ti n fomi ojúú sògbérè omo
Wón ní kó rúbo
Ó bí omo lópòlopò
Sùgbón kò séni tó mo babaa won
Ìwòrì ò rinkàn
Awo Olórèé Àgbon
A díá fún Ináagún
Níjó ti n fomi ojúú sògbérè omo
Ináagún la mò
A ò meni tó bí won.

Véase Iwori-Okana.